Mimido-Aaye

ọ̀pọ̀ alángbá ló da kùn dèé  lẹ̀
A ò mọ̀ èyí tí inú ro
A ò mọ̀ èyí tí inú run
ọ̀pọ̀ a fẹ́ ni lójú ló fata re sẹ́nu
Tí wọn kò fẹ́ wa dénú
A ò dẹ̀ bá wọn bínú

Bí mo ń ké Bí mo ń wí
Mo sọ sọ sọ
Tẹ́tí bẹ̀lẹ̀jẹ́
Bí mo ń ké ké ké
Tí mo ń wí wí wí
Mo sọ sọ sọ
Torí ayé le

I thought we were like
Captain Steve and falcon
ẹ̀yìn ìkùlé gan lọ̀tá wà

I didn't know that
Our case was like loci and Thor
Inú ilé laṣeni ń gbé

Once upon a time you put the smile on me
Was sweet and very bitterly
Dídùn ifòn, bóra dé eegun

You laid in wait to hunt me down
You missed the shot, I fled the scene
Lógun ọfẹ , mo ti d'afẹ́fẹ́

ọ̀pọ̀ alángbá ló da kùn dèé  lẹ̀
A ò mọ̀ èyí tí inú ro
A ò mọ̀ èyí tí inú run
ọ̀pọ̀ a fẹ́ ni lójú ló fata re sẹ́nu
Tí wọn kò fẹ́ wa dénú
A ò dẹ̀ bá wọn bínú

Bí mo ń ké Bí mo ń wí
Mo sọ sọ sọ
Tẹ́tí bẹ̀lẹ̀jẹ́
Bí mo ń ké ké ké
Tí mo ń wí wí wí
Mo sọ sọ sọ
Torí ayé le

Òpó tó yẹ kó mú ilé ró
Wá d'òpó tó lọ mú ilé wó
Ẹni agbé ojú okùn lé
Kò f'ibì kan kan Jọ ẹni agba
Ẹni a Ní kó kín ni lẹ́yìn
Túnbọ̀ wá lọ f'ẹ̀gún sọ́wọ́
Ayé Tótó Tótó ayé
Ayé Tótó àkámọrà

Aayé (3ce)

Click here to post comments

Join in and write your own page! It's easy to do. How? Simply click here to return to Post Your Lyrics.